Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í ṣe bí nípa ẹnìkan tí ó sẹ̀ ni ẹ̀bùn náà: Nítorí ìdájọ́ ti ipasẹ̀ ẹnìkan wá fún ìdálẹ́bi, ṣùgbọ́n ẹ̀bùn-ọ̀fẹ́ ti inú ẹ̀ṣẹ̀ púpọ̀ wá fún ìdáláre,

Ka pipe ipin Róòmù 5

Wo Róòmù 5:16 ni o tọ