Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 5:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì sì í ṣe bẹ́ẹ̀ nìkan, ṣùgbọ́n àwa ń ṣògo nínú Ọlọ́run nípa Olúwa wa Jésù Kírísítì, nípasẹ̀ ẹni tí àwa ti rí ìlàjà gbà nísinsìn yìí.

Ka pipe ipin Róòmù 5

Wo Róòmù 5:11 ni o tọ