Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a má rí i: kí Ọlọ́run jẹ́ olóòtọ́, àti olúkúlùkù ènìyàn jẹ́ èké; gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé:“Kí a lè dá ọ láre nínú ọ̀rọ̀ rẹ,ṣùgbọ́n kí ìwọ lè borí nígbà tí ìwọ bá wá sí ìdájọ́.”

Ka pipe ipin Róòmù 3

Wo Róòmù 3:4 ni o tọ