Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 3:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀nà ìṣògo dà? A ti mú un kúrò. Nípa òfin wo? Nípa iṣẹ́? Bẹ́ẹ̀ kọ́: Ṣùgbọ́n nípa òfin ìgbàgbọ́.

Ka pipe ipin Róòmù 3

Wo Róòmù 3:27 ni o tọ