Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má se dí iṣẹ́ Ọlọ́run lọ́wọ́ nítorí oúnjẹ. Gbogbo oúnjẹ ni ó mọ́, sùgbọ́n ohun búburú ni fún ẹni náà tí ó jẹ ohunkóhun tí ó le mú arákùnrin rẹ kọsẹ̀.

Ka pipe ipin Róòmù 14

Wo Róòmù 14:20 ni o tọ