Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ti kọ ìwé rẹ̀ pé:“ ‘Níwọ̀n ìgbà tí mo wà láàyè,’ ni Olúwa wí‘gbogbo eékún ni yóò wólẹ̀ fún mi;gbogbo ahọ́n ni yóò jẹ́wọ́ fún Ọlọ́run.’ ”

Ka pipe ipin Róòmù 14

Wo Róòmù 14:11 ni o tọ