Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé Mósè kọ ọ́ pé, “Kí ènìyàn tó lè rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ àti ìgbàlà (nípa òfin) gbà, ó ní láti ja àjàṣẹ́gun nínú gbogbo ìdánwò, kí ó sì wà láì dá ẹ̀ṣẹ̀ kan soso nínú gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀.”

Ka pipe ipin Róòmù 10

Wo Róòmù 10:5 ni o tọ