Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 10:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nípa ti Ísírẹ́lì ni ó wí pé,“Ní gbogbo ọjọ́ ni mo na ọwọ́ mi sí àwọnaláìgbọ́ràn àti aláríwísí ènìyàn.”

Ka pipe ipin Róòmù 10

Wo Róòmù 10:21 ni o tọ