Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 1:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n kún fún onírúurú àìṣòdodo gbogbo, àgbèrè, ìkà, ojúkòkòrò, àránkan; wọ́n kún fún ìlara, ìpànìyàn, ìjà, ìtànjẹ, ìwà-búburú; wọ́n jẹ́ afi-ọ̀rọ̀-kẹ́lẹ́-banijẹ́.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:29 ni o tọ