Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 1:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà Ọlọ́run fà wọ́n lé ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn wọn lọ́wọ́ láti máa ṣe ohun ìríra pẹ̀lú ara wọn èyí tí kò tọ́.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:24 ni o tọ