Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòótọ́, wọn ní òye nípa Ọlọ́run dáadáa, ṣùgbọ́n wọn kò yìn ín lógo bí Ọlọ́run, wọ́n kò sí dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀; wọ́n ń rò èrò aṣiwèrè, ọkàn òmùgọ̀ wọn sì ṣókùnkùn.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:21 ni o tọ