Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò tijú ìyìn rere Jésù, nítorí agbára Ọlọ́run ní ín ṣe láti gba gbogbo àwọn tí ó bá gbàgbọ́ là, ọ̀rọ̀ yìí ni a kọ́kọ́ wàásù sí àwọn Júù nìkan, ṣùgbọ́n nísinsin yìí fún aláìkọlà pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Róòmù 1

Wo Róòmù 1:16 ni o tọ