Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 9:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a lé ẹ̀mí èṣù náà jáde, ọkùnrin tí ó ya odi sì fọhùn. Ẹnu sì ya àwọn ènìyàn, wọ́n wí pé, “A kò rí irú èyí rí ní Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:33 ni o tọ