Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 9:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jésù sí i dé ilé ìjòyè náà, ó bá àwọn afọnfèrè àti ọ̀pọ̀ ènìyàn tí ó ń paríwó.

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:23 ni o tọ