Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 9:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò sí ẹni tí í fi ìrépé aṣọ tutun lẹ ògbólògbó ẹ̀wù; nítorí èyí tí a fi lẹ̀ ẹ́ yóò ya ní ojú lílẹ̀, aṣọ náà yóò sì ya púpọ̀ sì i ju ti ìṣáájú lọ.

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:16 ni o tọ