Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 8:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Balógun ọ̀rún náà dahùn, ó wí pé, “Olúwa, èmi kò yẹ ní ẹni tí ìwọ ń wọ̀ abẹ́ òrùlé rẹ̀, ṣùgbọ́n sọ kìkì ọ̀rọ̀ kan, a ó sì mú ọmọ-ọ̀dọ̀ mi láradá.

Ka pipe ipin Mátíù 8

Wo Mátíù 8:8 ni o tọ