Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 8:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n kígbe lóhùn rara wí pé, “Kí ní ṣe tàwa tìrẹ, Ìwọ Ọmọ Ọlọ́run? Ìwọ ha wá láti dá wa lóró ṣáájú ọjọ́ tí a yàn náà?”

Ka pipe ipin Mátíù 8

Wo Mátíù 8:29 ni o tọ