Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 8:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùkọ́ òfin kan sì tọ̀ ọ́ wá, ó wí fún un pé, “Olùkọ́, èmi ó má tọ̀ ọ́ lẹ́yìn níbikíbi tí ìwọ bá ń lọ.”

Ka pipe ipin Mátíù 8

Wo Mátíù 8:19 ni o tọ