Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì wí fún yín, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni yóò ti ìha ìlà-oòrùn àti ìhà iwọ̀-oòrùn wá, wọ́n á sì bá Ábúráhámù àti Ísáákì àti Jákọ́bù jẹun ní ìjọba ọ̀run.

Ka pipe ipin Mátíù 8

Wo Mátíù 8:11 ni o tọ