Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 7:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kì í ṣe gbogbo ẹni tó ń pè mí ní, ‘Olúwa, Olúwa,’ ni yóò wọ ìjọba ọ̀run, bí kò ṣe ẹni tó bá ń ṣe ìfẹ́ baba mi tí ń bẹ ní ọ̀run.

Ka pipe ipin Mátíù 7

Wo Mátíù 7:21 ni o tọ