Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ máa ba ẹnu-ọ̀nà tóótó wọlé; gbòòrò ni ẹnu-ọ̀nà náà, àti oníbùú ni ojú ọ̀nà náà tí ó lọ sí ibi ìparun, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn ẹni tí ń bá ibẹ̀ wọlé.

Ka pipe ipin Mátíù 7

Wo Mátíù 7:13 ni o tọ