Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 6:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ wo àwọn ẹyẹ inú afẹ́fẹ́; wọn kì í gbìn, bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í kórè, bẹ́ẹ̀ ni wọn kì í kó jọ sínú àká, ṣíbẹ̀ Baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run ń bọ́ wọn. Ẹ̀yin kò ha níye lórí jù wọ́n lọ bí?

Ka pipe ipin Mátíù 6

Wo Mátíù 6:26 ni o tọ