Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 6:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kò sìí ẹnìkan tí ó lè sin ọ̀ga méjì. Òun yóò yà kórìíra ọ̀kan tí yóò fẹ́ràn èkejì, tàbí kí ó fara mọ́ ọ̀kan kí ó sì yan èkejì ní ìpọ̀sì. Ẹ̀yin kò lè sin Ọlọ́run àti owó papọ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 6

Wo Mátíù 6:24 ni o tọ