Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 6:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Má ṣe to àwọn ìṣúra jọ fún ara rẹ ní ayé yìí, níbi tí kòkòrò ti le jẹ ẹ́, tí ó sì ti le dípẹtà àti ibi tí àwọn olèlè fọ́ tí wọ́n yóò sì jí i lọ.

Ka pipe ipin Mátíù 6

Wo Mátíù 6:19 ni o tọ