Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí ẹ̀yin bá gbààwẹ̀, ẹ má ṣe fa ojú ro bí àwọn àgàbàgebè ṣe máa ń ṣe nítorí wọn máa ń fa ojú ro láti fi hàn àwọn ènìyàn pé àwọn ń gbààwẹ̀. Lóòótọ́ ni mo wí fún yín wọn ti gba èrè wọn ní kíkún.

Ka pipe ipin Mátíù 6

Wo Mátíù 6:16 ni o tọ