Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 5:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀yin bá fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn yín nìkan, èrè kí ni ẹ̀yin ní? Àwọn agbowó-òde kò ha ń ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́?

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:46 ni o tọ