Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 5:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ojú rẹ ọ̀tún bá mú ọ dẹ́sẹ̀, yọ ọ́ jáde, kí ó sì sọ ọ́ nù. Ó sàn kí ẹ̀ya ara rẹ kan ṣègbé, ju kí a gbé gbogbo ara rẹ jù sínú iná ọ̀run àpáàdì.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:29 ni o tọ