Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 5:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bá ọ̀tá rẹ làjà kánkán, ẹni tí ó ń gbé ọ lọ sílé ẹjọ́. Ṣe é nígbà ti ó wà ní ọ̀nà pẹ̀lú rẹ, bí bẹ́ẹ̀ kọ́ yóò fà ọ́ lé onídajọ lọ́wọ́, onídájọ́ yóò sí fá ọ lé àwọn ẹ̀sọ́ lọ́wọ́, wọ́n a sì sọ ọ́ sínú túbú.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:25 ni o tọ