Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 5:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bákan náà, ẹ jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ yín kí ó mọ́lẹ níwájú ènìyàn, kí wọ́n lè máa rí iṣẹ́ rere yín, kí wọn lè máa yin baba yín tí ń bẹ ní ọ̀run lógo.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:16 ni o tọ