Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí pé, “Bí ìwọ̀ bá jẹ́ ọmọ Ọlọ́run, Bẹ́ sílẹ̀ fún ara rẹ. A sa ti kọ̀wé rẹ̀ pé:“ ‘Yóò pàṣẹ fún àwọn ańgẹ́lì rẹ̀ nítorí tìrẹwọn yóò sì gbé ọ sókè ni ọwọ́ wọnkí ìwọ kí ó má baà fi ẹsẹ̀ rẹ gbún òkúta.’ ”

Ka pipe ipin Mátíù 4

Wo Mátíù 4:6 ni o tọ