Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 4:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkìkí rẹ̀ sì kàn yí gbogbo Síríà ká; wọ́n sì gbé àwọn aláìsàn tí ó ní onírúurú àrùn, àwọn tí ó ní ìnira ẹ̀mí èṣù, àti àwọn ti o ní wárápá àti àwọn tí ó ní ẹ̀gbà; ó sì wò wọ́n sàn.

Ka pipe ipin Mátíù 4

Wo Mátíù 4:24 ni o tọ