Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Irun ràkúnmí ni a fi hun aṣọ Jòhánù, awọ ni ó sì fi di àmùrè ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀. Eṣú àti oyin ìgàn sì ni oúnjẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 3

Wo Mátíù 3:4 ni o tọ