Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi fi omi bamitíìsì yín fún ìrónúpìwàdà. Ṣùgbọ́n lẹ́yìn mi ẹnìkan tí ó lágbára jù mí lọ ń bọ̀, bàtà ẹni tí èmi kò tó gbé. Òun ni yóò fi Ẹ̀mí Mímọ́ àti iná bamitíìsì yín.

Ka pipe ipin Mátíù 3

Wo Mátíù 3:11 ni o tọ