Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 28:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn obìnrin náà sì ti ń lọ sí ìlú, díẹ̀ nínú àwọn olùṣọ́ tí wọ́n ti ń ṣọ́ ibojì lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà.

Ka pipe ipin Mátíù 28

Wo Mátíù 28:11 ni o tọ