Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 27:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́sẹ̀ kan náà, ọ̀kan nínú wọn sáré, ó mú kànrìkàn, ó tẹ̀ ẹ́ bọ inú ọtí kíkan. Ó fi lé orí ọ̀pá, ó gbé e sókè láti fi fún un mu.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:48 ni o tọ