Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 27:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n kẹ́gàn Rẹ̀ pé, “Ó gba àwọn ẹlòmíràn là, kò sí lè gba ara rẹ̀. Ìwọ ọba àwọn Ísírẹ̀lì? Sọ̀ kalẹ̀ láti orí àgbélébùú nísinsìn yìí, àwa yóò sì gbà ọ́ gbọ́.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:42 ni o tọ