Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 26:57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó mú Jésù fà á lọ sí ilé Káíáfà, olórí àlùfáà, níbi ti àwọn olúkọ́ òfin àti gbogbo àwọn àgbààgbà Júù péjọ sí.

Ka pipe ipin Mátíù 26

Wo Mátíù 26:57 ni o tọ