Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 26:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun lọ sí iwájú díẹ̀ sí i, ó sì dojú bolẹ̀, ó sì gbàdúrà pé, “Baba mi, bí ó bá ṣeé se, jẹ́ kí a mú aago yìí ré mi lórí kọjá, ṣùgbọ́n ìfẹ́ tìrẹ ni mo fẹ́ kí ó ṣẹ, kì í ṣe ìfẹ́ tèmi.”

Ka pipe ipin Mátíù 26

Wo Mátíù 26:39 ni o tọ