Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 26:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ-Ènìyàn ń lọ bí a ti kọ̀wé nípa rẹ̀: ṣùgbọ́n ègbé ni fún ọkùnrin náà lọ́wọ́ ẹni tí a ó ti fi Ọmọ ènìyàn hàn! Ìbá kúkú sàn fún ẹni náà, bí a kò bá bí.”

Ka pipe ipin Mátíù 26

Wo Mátíù 26:24 ni o tọ