Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 26:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kìn-ín-ní àjọ àkàrà àìwú, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn tọ Jésù wá pé, “Níbo ni ìwọ fẹ́ kí a pèsè sílẹ̀ láti jẹ àsè ìrékọjá?”

Ka pipe ipin Mátíù 26

Wo Mátíù 26:17 ni o tọ