Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 26:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà tí Jésù ti parí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yin rẹ̀, ó wí fún wọn pé,

2. “Bí ẹ̀yin tí mọ̀ ní ọjọ́ méjì sí i, àjọ ìrékọjá yóò bẹ̀rẹ̀. Àti pé, a ó fi Ọmọ-Ènìyàn lé ni lọ́wọ́, a ó sì kàn mí mọ́ àgbélébùú.”

Ka pipe ipin Mátíù 26