Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 25:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́gbọ́n márùn-ún dáhùn pé, bẹ́ẹ̀ kọ́; kí ó má baà ṣe aláìtó fún àwa àti ẹ̀yin, ẹ kúkú tọ àwọn tí ń tà á lọ, kí ẹ sì rà fún ara yín.

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:9 ni o tọ