Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 25:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọba náà yóò sì dáhùn yóò sì wí fún wọn pé, ‘lóòótọ́ ni mo wí fún yín pé níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀yin ṣe nǹkan wọ̀nyí fún àwọn arákùnrin mi yìí tí o kéré jú lọ, ẹ̀ ń ṣe wọn fún mi ni.’

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:40 ni o tọ