Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 24:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lójú kan náà lẹ́yìn ìpọ́njú ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì,“ ‘ni oòrùn yóò ṣókùnkùn,òṣùpá kì yóò sì fi ìmọ́lẹ̀ rẹ hàn;àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run yóò já sílẹ̀,agbára ojú ọ̀run ni a ó mì tìtì.’

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:29 ni o tọ