Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 24:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jésù ti ń kúrò ni tẹ́ḿpílì, àwọn ọmọ-ẹ̀yin rẹ̀ tọ̀ ọ́ wá, wọ́n fẹ́ fi ẹwà tẹ́ḿpílì náà hàn án.

Ka pipe ipin Mátíù 24

Wo Mátíù 24:1 ni o tọ