Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 23:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun gbogbo tí wọ́n ń ṣe, wọ́n ń ṣe é kí àwọn ènìyàn ba à lè rí wọn ni: Wọ́n ń sọ fílákítérì wọn di gbígbòòrò. Wọ́n tilẹ̀ ń bùkún ìṣẹ́tí aṣọ oyè wọn nígbà gbogbo kí ó ba à lè máa tóbi sí i.

Ka pipe ipin Mátíù 23

Wo Mátíù 23:5 ni o tọ