Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègbé ni fún yín ẹ̀yin olùkọ́ òfin àti Farisí, ẹ̀yin àgàbàgebè! nítorí ẹ̀yin rin yí ilẹ̀ àti òkun ká láti yí ẹnì kan lọ́kàn padà, ṣùgbọ́n ẹ̀yin ń sọ ọ́ di ọmọ ọ̀run àpáàdì ní ìlọ́po méjì ju ẹ̀yin pàápàá.

Ka pipe ipin Mátíù 23

Wo Mátíù 23:15 ni o tọ