Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 23:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà náà ni Jésù wí fún ọ̀pọ̀ ènìyàn àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé:

2. “Àwọn olùkọ́ òfin àti àwọn Farisí jòkòó ní ipò Mósè,

Ka pipe ipin Mátíù 23