Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 22:43-46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

43. Ó sì wí fún wọn pé, “Kí ni dé tí Dáfídì, tí ẹ̀mí ń darí, pè é ní ‘Olúwa’? Nítorí ó wí pé,

44. “ ‘Olúwa sọ fún Olúwa mi,“Jòkòó ní ọwọ́ ọ̀tún mitítí tí èmi yóò fi fi àwọn ọ̀ta rẹsí abẹ́ ẹsẹ̀ rẹ.” ’

45. Ǹjẹ́ bí Dáfídì bá pè é ni ‘Olúwa,’ báwo ni òun se lè jẹ́ ọmọ rẹ̀?”

46. Kò sí ẹnì kan tí ó lè sọ ọ̀rọ̀ kan ni ìdáhùn, kò tún sí ẹni tí ó tún bí i léèrè ohun kan mọ́ láti ọjọ́ náà mọ́.

Ka pipe ipin Mátíù 22