Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mátíù 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rán àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀ láti lọ sọ fún àwọn tí a ti pè tẹ́lẹ̀ pé àsìkò ti tó láti wá sí ibi àsè. Ṣùgbọ́n gbogbo wọn kọ̀ láti wá.

Ka pipe ipin Mátíù 22

Wo Mátíù 22:3 ni o tọ